background cover of music playing
Oluwa - TMP Offisial

Oluwa

TMP Offisial

00:00

03:15

Similar recommendations

Lyric

Oh lord of mercy

Paranranrara

Imole

Oluwa jowo o, Oluwa 3ce

Oluwa sign soro me o (oluwa sign soro me o)

Oluwa dakun se temi funmi

Oluwa gbo adura me o (Oluwa gbo adura me o)

Baba so n gbohun me o

Oluwa bless hustle me o (Oluwa bless hustle me)

Oluwa dakun maje n lo lofo

Igba wo ni ire ma kan me o (Igba wo ni ire ma kan me o)

Baba so n gbohun me o

Oh oh oh baba ti ba mi se

Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo

Ki n lo ma jubilate, yea yea

Baba ti ba mi se

Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo

Ki n lo ma celebrate, yea yea

Ko si ewu funwa, omo Olorun lawa

E o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo Adura wa

Ko le doju ti awa

Aiymoye pains ti mo go thru

Aiymoye dreams ti mo chase ti ko come true

Aiymoye emi nicca se to de ti sonu

Base on say won fe pa owo yi se won de fe hustle

Mo bere orin kiko layi si eni to mo mi

Aiymoye rap battle ti molo to je pe won na mi

Ere lo pe abi woh no be small story (small story)

Sugbon today me i give God the big glory (the glory)

Aiymoye oro werray to ti so leyin me

Sugbon nisiyin wo so pe awon fe feature me

Elo lo wa nle won so pe no money

Ti o ba ti si ooo wa ma lole bye bye

Ko si ewu funwa, omo Olorun lawa

E o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo Adura wa

Ko le doju ti awa

Oh oh oh baba ti ba mi se

Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo

Ki n lo ma jubilate, yea yea

Baba ti ba mi se

Oni ki n ma lo, ki n ma lo, ki n ma lo

Ki n lo ma celebrate, yea yea

Baba lo ni ki n ma lo... eh

Owun lo ni ki n ma lo...

Ko ma de si ewu lono

Baba lo ni ki n ma lo ooo

Owun lo ni ki n ma lo

Ki n somo lo, ki n gbomo lo

Nine Aye

Imole

Ko ma de si ewu lono

- It's already the end -