background cover of music playing
Iba - Sola Allyson

Iba

Sola Allyson

00:00

05:45

Similar recommendations

Lyric

Iba ree nima faayee mii ju

Sinsin ooo lemi a fii gbamise

Sebi yen naani iyen gangan shaa loda mii fun

Eni ayeraye too nii gba mii oo mofogoo foruko ree

Afuye geegee tiko seegbe, jibini jibinii bii

Atee ileke kabiesi mosebare ooo oba too

Juu gbogbo oba loo

Juu gbogbo oba loo

Iba ooo ibaa ooo

Mosebare ooo mosebare moforii balee Mogbowoo

Sokee kabiesi moo sebare Oba too juu gbogbo oba loo

Mosebare ooo mosebare ree nirele okan miiii nimo waari

Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Emi'n sebare ooo mosebare

Moforii balee mogbowoo sokee kabiesi

Moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Taloo lee soo talo lee kaawon awon Irawo

Towa loju orun egbe isiro lewon kee sofun waa

Awon erupe inu okun talo lee soo talo moo yee ewa iseda toyi waa kaa

Iyanu fun dudu Iyanu fun funfun

Ose feni too gban ati enii too goo

Kabiesi ooo mosebare ree oba too juu gbogbo oba loo

Afuye geegee tii ooo seegbe jibini jibinii bii atee ileke

Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Mosebare ooo mosebare ree oba too juu gbogbo oba loo

Gbogbo ayee gboun sokee won sebare

Oun gbogbo seba fun ooo mofogoo foruko ree

Oju mii tiri eti mii tii gbooo Iyanu ree yii ayee kaa

Mogboo ninu eri awon eyan mimo

Mori ninu itan emi gangan nii itan

Gbogbo isee ree daadaadaa niii aburu kankan ooo too doo ree waa

Oun gbogbo loleyii pade sugbon rara toodoodoo ree koo

Kabiesi ooo mosebare ree ooo oba too juu gbogbo oba loo

Afuye geegee tii ooo seegbe jibini jibinii bii atee ileke

Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Mosebare ooo mosebare ree moforii balee mogbowoo sokee kabiesi

Moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Mosebare ooo mosebare nirele okan miiii mowarii

Kabiesi moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Oba too juu gbogbo oba loo kabiesi

Moo sebare oba too juu gbogbo oba loo

Emi ooo maa fiibukun foruko ree

Oba too juu gbogbo oba loo

Nigba gbogbo lemi ooo fiiyin fun ooo see

Oba too juu gbogbo oba loo

Oluwa oro ree yii aye kaa

Oba too juu gbogbo oba loo

Mojewo ree

Mojewo iwo nikan loluwa ooo oba too juu gbogbo oba loo

You are beautiful beyond description ewa ree koja ogbon orii miiii

Oba too juu gbogbo oba loo

You are wonderful beyond comprehension oro ree koja oyee mii

Oba too juu gbogbo oba loo

- It's already the end -