00:00
06:45
Ẹ̀kọ́ àìmọ̀lára tó wúlò nípa orin yìí kò sí lọ́wọ́lọwọ́.
Hm-mm-mm-mm
Oh-oh-oh-oh-oh-oh
Ay-ay-ay-ay-ay-ay
You are worthy, You are worthy, You are worthy of my praise
You are worthy, You are worthy, You are worthy of my praise
Ẹlẹburuikẹ o
O-ran'mọ-niṣẹ-fayati o, arani-banilọ o, You are worthy
Ọba to gba mi la o, ọlọwọ ina o
Ìwọ nikan l'ogo ye o, You are worthy
(You are worthy) You are worthy (ìwọ lo ni iyin at'ọla)
You are worthy (ni mo ṣe de mo wa fi fun ọ)
You are worthy (ẹlẹmi iun mi, Baba) of my praise (Baba awọn baba)
Lion of the Tribe of Juda, kinging in His majesty
Ruler of the universe, I tremble at Your feet
Lion of the Tribe of Juda, kinging in His majesty
Ruler of the universe, worthy of our worship
(Iwọ to n j'ọba lori gbogbo aye)
You are worthy (iṣọ aye, iṣọ ẹmi ẹda gbogbo-)
You are worthy (olori áńgẹlì, olori ọrun)
You are worthy (ìwọ to n dari aye at'ọrun pọ) of my praise
(Ìwọ to da oorun to di'ju ri) You are worthy
(Kọmibọki ọrọ to d'aye at'ọrun) You are worthy
(Ipanla gbogbo aye) You are worthy (oke ati'lẹ ẹmi-) of my praise
(Fi gbogbo ọla)
Ọlọla to ga ju lọ, ọlọrọ to pọju lọ
Ologo to ga ju, You are worthy
Ọba to ju gbogbo ọba lọ
Ìjọba ni bi gbogbo, olori aye, nisalẹ ilẹ, alainipẹkun (alainipẹkun ni ọ)
You are worthy (Baba, mẹta, lọkan)
You are worthy (ajulọ to n bẹ nibi gbogbo ẹda eeniyan)
You are worthy (aara ọrun wọn rii) of my praise
(Ara aye ri ọ, tisalẹ, ilẹ wọn mọ da-) You are worthy
(Amọdaju ẹda gbogbo) You are worthy
(Niun ẹmi at'ara lati mọ ọ) You are worthy
(Lafi ri pe iwọ nikan l'ọpe ye o) of my praise
(Iba o-o-o)
O f'ọrun nikan ṣe kiki da wura
Ọda ọrun at'aye pẹlu ara, ọtọ
Ẹbọ mi aji saa, aji tọla, mo gboṣuba f'ogo rabande
Ìbẹrẹ ogo arin ogo, olounkangun ogo igbẹyin ogo
Ẹni ti gbogbo aye yi o pada wa bọ
Kabiesi o (mo ṣe Kabiesi)
Araye k'ọba ni kabiesi
Wọn ni, "Kade pe lori, ki bata pe lẹsẹ o" (bẹẹni)
Ìwọ nikan ni kabiesi (yeah-ah), ta o gbodo sọ pe k'ade pe lori fun (ewo!)
A o gbodo pe ki bata pe lẹsẹ (lai-lai)
Ṣade ta o mọ gba to de sori rẹ
Ṣe bata ta o mo gba to wọ ẹsẹ rẹ (alagbara giga tangoro)
T'áńgẹlì kan o mọ (bẹẹni wọn o mọ)
Gbogbo awọn t'ọrun n juba (wọn juba)
Ìwọ nikan ni wọn bọ o (mo ba wọn bọ ọ)
Ki lo wa ṣe mi, ṣaye mi (ki ni yi o ṣe mi?)
Ti nu o ni maa bọ ọ? (Laiye, fabada, ki ma rii)
Gba ogo ati ọla (gba o)
Gba ogo ati iyin (gba o)
Ìwọ nikan lo tọ si (You alone at worthy, Lord)
Gba ogo ati ọla
Gba ogo ati iyin
Ìwọ nikan lo tọ si (agadagodo ẹmi gbogbo eniyan)
Gba ogo ati ọla (ẹni to lẹmi)
Gba ogo ati iyin (opa kanwo kanye)
Ìwọ nikan lo tọ si (Ọba ti n gẹṣin lori)
(Eleni ironu eda koko) (patapinra ọla)
Ìwọ nikan lo tọ si
(Oniye ara ọtọ) gba ogo ati ọla
Gba ogo ati iyin (gba o)
Ìwọ nikan lo tọ si (elemi iun ẹda gbogbo)
Gba ogo ati ọla (gba)
Gba ogo ati iyin, Ìwọ nikan lo tọ si
(Ẹni to fi ẹmí ẹ rubo fun emi)
Gba ogo ati ola (gba o)
Gba ogo ati iyin (gba ogo)
Ìwọ nikan lo tọ si (tani n ba tun fi fun?)
Gba gbogbo ogo, oni ba ẹnikẹni pin
Ìwọ nikan lo tọ si
You are worthy (o worthy), You are worthy (o worthy o)
You are worthy (ìwọ t'áńgẹlì n bọ lo jọjọ) of my praise
(Agbagba mẹrìnlelógún ṣi ade kalẹ) You are worthy
(Wọn bọ ìwọ nikan tori ìwọ nikan lo tọ si) You are worthy
(Ay-ay, ẹda gbogbo ti n bẹ nísàlẹ) You are worthy
(Ìwọ nikan ni wọn dóbalẹ fun) of my praise
(Bẹẹ lo titun si lójoojúmọ) You are worthy
(Bẹẹ lo n yatọ si niun ogo ìtẹ) You are worthy
(Itẹ ologo to n dan gbinrin) You are worthy
(Ogo to bi ogo, to da ogo, to pọn-ọn ogo) of my praise
Ìwọ nikan lo worthy o
Mo b'ọla fun ọ, mo fiyin ọ
Mo f'ogo ọ
Mo dara pọ mọ awọn t'ọrun lati sọ wi pe
O ṣe tori o worthy o